Gba ayé là

ní ìrọrùn ìbusùn rẹ

A nílò ìrànwọ́ rẹ!

Àwọn ju bí 400 mílíónù ènìyàn ni o ńlò, àtìlẹ́hìn Mozilla ni àwọn ìfi-ara-ẹni lẹ̀ ṣe, ó sì ṣe pàtàkì ju tẹ́lẹ̀. Ibi tí o ti kàn ọ́ nìyí.

Kíni ìdí ìrànwọ́ mi?

Ran mílíónù àwọn olùṣàmúlò lọ́wọ́ láti rí èyí tí ó dára ni aayò ìgbàwálẹ̀. Ìdasí rẹ yóò dé ọ̀dọ̀ àwọn mílíónù olùṣàmúlò lágbaayé, o sì le ṣé ní ìrọrùn ìbùsùn rẹ!

Yan ọ̀nà láti kópa

Nípa Wa

Àtìlẹ́hìn Mozilla jẹ́ àwùjọ àwọn afàrajìn onítara àti òṣìṣẹ́ tí o ń gbìyànjú láti sàtìlẹ́hìn àwọn olùṣàmúlò ni gbogbo àgbayé. Darapọ̀ mọ́ wa fún gbìdánẁo máni gbàgbé!
Béèrè ìbéèrè

Ṣé ìṣòro pẹ̀lú àbájáde Mozilla tí o fẹ́ ṣèrànwọ́ wà?